Yoruba ni bi ọba kan ko ba ku, omiran kii jẹ, bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu igbesẹ yiyan ọmọ oye tuntun si ipo Awujalẹ tilẹ Ijebu. Bi ẹ ko ba gbagbe, ọjọ Kẹtala osu Keje ọdun 2025 ni Awujalẹ ti Ijebu Ode, Ọba ...
Wọn ti gbe ade ati ọpa aṣẹ fun Olubadan tuntun, Sẹnetọ Lekan Balogun nilu Ibadan lọjọ Ẹti. Gbagede gbọngan nla Mapo ni Ọjaaba ni ayẹyẹ igbọpa aṣẹ Ọba Lekan Balogun Okumadade Keji ti waye gẹgẹ bii ...